Surah Al-Baqara Verse 173 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqaraإِنَّمَا حَرَّمَ عَلَيۡكُمُ ٱلۡمَيۡتَةَ وَٱلدَّمَ وَلَحۡمَ ٱلۡخِنزِيرِ وَمَآ أُهِلَّ بِهِۦ لِغَيۡرِ ٱللَّهِۖ فَمَنِ ٱضۡطُرَّ غَيۡرَ بَاغٖ وَلَا عَادٖ فَلَآ إِثۡمَ عَلَيۡهِۚ إِنَّ ٱللَّهَ غَفُورٞ رَّحِيمٌ
Ohun ti (Allahu) se ni eewo fun yin ni okunbete, eje, eran elede ati ohun ti won pe oruko miiran le lori yato si (oruko) Allahu. Sugbon eni ti won ba fi inira (ebi) kan, yato si eni t’o n wa eewo kiri ati olutayo-enu-ala, ko si ese fun un. Dajudaju Allahu ni Alaforijin, Asake-orun