Surah Al-Baqara Verse 184 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqaraأَيَّامٗا مَّعۡدُودَٰتٖۚ فَمَن كَانَ مِنكُم مَّرِيضًا أَوۡ عَلَىٰ سَفَرٖ فَعِدَّةٞ مِّنۡ أَيَّامٍ أُخَرَۚ وَعَلَى ٱلَّذِينَ يُطِيقُونَهُۥ فِدۡيَةٞ طَعَامُ مِسۡكِينٖۖ فَمَن تَطَوَّعَ خَيۡرٗا فَهُوَ خَيۡرٞ لَّهُۥۚ وَأَن تَصُومُواْ خَيۡرٞ لَّكُمۡ إِن كُنتُمۡ تَعۡلَمُونَ
(E gba aawe naa) fun awon ojo ti o ni onka. (Sugbon) enikeni ninu yin ti o ba je alaisan, tabi o wa lori irin-ajo, (o maa san) onka (gbese aawe re) ni awon ojo miiran. Ati pe itanran (iyen) fifun mekunnu ni ounje l’o di dandan fun awon t’o maa fi inira gba aawe. Enikeni ti o ba finnufindo se (alekun) ise oloore, o kuku loore julo fun un. Ati pe ki e gba aawe loore julo fun yin ti e ba mo