Surah Al-Baqara Verse 189 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqara۞يَسۡـَٔلُونَكَ عَنِ ٱلۡأَهِلَّةِۖ قُلۡ هِيَ مَوَٰقِيتُ لِلنَّاسِ وَٱلۡحَجِّۗ وَلَيۡسَ ٱلۡبِرُّ بِأَن تَأۡتُواْ ٱلۡبُيُوتَ مِن ظُهُورِهَا وَلَٰكِنَّ ٱلۡبِرَّ مَنِ ٱتَّقَىٰۗ وَأۡتُواْ ٱلۡبُيُوتَ مِنۡ أَبۡوَٰبِهَاۚ وَٱتَّقُواْ ٱللَّهَ لَعَلَّكُمۡ تُفۡلِحُونَ
Won n bi o leere nipa iletesu. So pe: “Ohun ni (onka) akoko fun awon eniyan ati (onka akoko fun) ise Hajj. Ki i se ise rere (fun yin) lati gba eyin-inkule wonu ile, sugbon (oluse) rere ni eni ti o ba beru (Allahu). E gba enu-ona wonu ile. Ki e si beru Allahu nitori ki e le jere