Surah Al-Baqara Verse 19 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqaraأَوۡ كَصَيِّبٖ مِّنَ ٱلسَّمَآءِ فِيهِ ظُلُمَٰتٞ وَرَعۡدٞ وَبَرۡقٞ يَجۡعَلُونَ أَصَٰبِعَهُمۡ فِيٓ ءَاذَانِهِم مِّنَ ٱلصَّوَٰعِقِ حَذَرَ ٱلۡمَوۡتِۚ وَٱللَّهُ مُحِيطُۢ بِٱلۡكَٰفِرِينَ
Tabi (apejuwe won) da bi ojo nla ti n ro lati sanmo. O mu awon okunkun, ara sisan ati monamona lowo. Won n fi ika won sinu eti won nitori igbe ara sisan fun iberu iku. Allahu si yi awon alaigbagbo ka