Surah Al-Baqara Verse 223 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqaraنِسَآؤُكُمۡ حَرۡثٞ لَّكُمۡ فَأۡتُواْ حَرۡثَكُمۡ أَنَّىٰ شِئۡتُمۡۖ وَقَدِّمُواْ لِأَنفُسِكُمۡۚ وَٱتَّقُواْ ٱللَّهَ وَٱعۡلَمُوٓاْ أَنَّكُم مُّلَٰقُوهُۗ وَبَشِّرِ ٱلۡمُؤۡمِنِينَ
Awon obinrin yin, oko ni won fun yin. E lo s’inu oko yin bi e ba se fe, ki e si ti (ise rere) siwaju fun emi ara yin. E beru Allahu. Ki e mo pe dajudaju e maa pade Re. Ki o si fun awon onigbagbo ododo ni iro idunnu