Surah Al-Baqara Verse 271 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqaraإِن تُبۡدُواْ ٱلصَّدَقَٰتِ فَنِعِمَّا هِيَۖ وَإِن تُخۡفُوهَا وَتُؤۡتُوهَا ٱلۡفُقَرَآءَ فَهُوَ خَيۡرٞ لَّكُمۡۚ وَيُكَفِّرُ عَنكُم مِّن سَيِّـَٔاتِكُمۡۗ وَٱللَّهُ بِمَا تَعۡمَلُونَ خَبِيرٞ
Ti e ba safi han awon saraa, o kuku dara. Ti e ba si fi pamo, ti e lo fun awon alaini, o si dara julo fun yin. Allahu si maa pa awon iwa aidaa yin re fun yin. Allahu si ni Alamotan nipa ohun ti e n se nise