Surah Al-Baqara Verse 277 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqaraإِنَّ ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ وَعَمِلُواْ ٱلصَّـٰلِحَٰتِ وَأَقَامُواْ ٱلصَّلَوٰةَ وَءَاتَوُاْ ٱلزَّكَوٰةَ لَهُمۡ أَجۡرُهُمۡ عِندَ رَبِّهِمۡ وَلَا خَوۡفٌ عَلَيۡهِمۡ وَلَا هُمۡ يَحۡزَنُونَ
Dajudaju awon t’o gbagbo ni ododo, ti won se awon ise rere, ti won kirun, ti won si yo Zakah, esan won n be fun won ni odo Oluwa won. Ko si ipaya fun won. Won ko si nii banuje