Surah Al-Baqara Verse 41 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqaraوَءَامِنُواْ بِمَآ أَنزَلۡتُ مُصَدِّقٗا لِّمَا مَعَكُمۡ وَلَا تَكُونُوٓاْ أَوَّلَ كَافِرِۭ بِهِۦۖ وَلَا تَشۡتَرُواْ بِـَٔايَٰتِي ثَمَنٗا قَلِيلٗا وَإِيَّـٰيَ فَٱتَّقُونِ
E gbagbo ninu ohun ti Mo sokale, ti o n fi ohun t’o je ododo rinle nipa eyi t’o wa pelu yin. E ma se je eni akoko ti o maa sai gbagbo ninu re. E ma se ta awon ayah Mi l’owo pooku.Emi nikan soso ni ki e si beru