UAE Prayer Times

  • Dubai
  • Abu Dhabi
  • Sharjah
  • Ajman
  • Fujairah
  • Umm Al Quwain
  • Ras Al Khaimah
  • Quran Translations

Surah Al-Hajj Verse 52 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Surah Al-Hajj

وَمَآ أَرۡسَلۡنَا مِن قَبۡلِكَ مِن رَّسُولٖ وَلَا نَبِيٍّ إِلَّآ إِذَا تَمَنَّىٰٓ أَلۡقَى ٱلشَّيۡطَٰنُ فِيٓ أُمۡنِيَّتِهِۦ فَيَنسَخُ ٱللَّهُ مَا يُلۡقِي ٱلشَّيۡطَٰنُ ثُمَّ يُحۡكِمُ ٱللَّهُ ءَايَٰتِهِۦۗ وَٱللَّهُ عَلِيمٌ حَكِيمٞ

A ko ran Ojise kan tabi Anabi kan nise siwaju re afi ki o je pe nigba ti o ba soro, Esu maa ju (nnkan) sinu oro re. Nitori naa, Allahu yoo pa ohun ti Esu n ju sinu re re. Leyin naa, O maa fi ododo awon ayah Re rinle. Allahu si ni Onimo, Ologbon. won ko ni imo oloookan nipa al-Ƙur’an ati hadith sugbon won mo iro funfun balau pa mo esin ’Islam. Ise won yii si se weku oro ti Allahu (subhanahu wa ta'ala) so nipa won ninu surah al-Baƙorah; 2: 78. eni ti Esu ba n gbenu re soro bi ko je were ti ko se e fi se eri afi hadith eyo kan pere. Iyen ni pe gbogbo hadith t’o n so nipa pe Anabi (sollalahu 'alayhi wa sallam) so pe “Iwonyen ni awon eye agba. Ati pe ireti wa ninu isipe ti won maa se.” je hadith t’o le patapata. Amo eyi ti o fese rinle ninu won ko tayo eyi ti o wa ninu sohihu-l-Bukoriy egbawa Bukoriy ti yanju oro naa. Ko si si oro “awon eye agba meta” kan kan ninu re. Nitori naa hadith ko baa le ni igba lori oro kan naa

Author: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni


<< Surah 22 Verse 51
>> Surah 22 Verse 53

Yoruba Translations by other Authors


Yoruba Translation By Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Yoruba Translation By Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Popular Areas
Apartments for rent in Dubai Apartments for rent Abu Dhabi Villas for rent in Dubai House for rent Abu Dhabi Apartments for sale in Dubai Apartments for sale in Abu Dhabi Flat for rent Sharjah
Popular Searches
Studios for rent in UAE Apartments for rent in UAE Villas for rent in UAE Apartments for sale in UAE Villas for sale in UAE Land for sale in UAE Dubai Real Estate
Trending Areas
Apartments for rent in Dubai Marina Apartments for sale in Dubai Marina Villa for rent in Sharjah Villa for sale in Dubai Flat for rent in Ajman Studio for rent in Abu Dhabi Villa for rent in Ajman
Trending Searches
Villa for rent in Abu Dhabi Shop for rent in Dubai Villas for sale in Ajman Studio for rent in Sharjah 1 Bedroom Apartment for rent in Dubai Property for rent in Abu Dhabi Commercial properties for sale
© Copyright Dubai Prayer Time. All Rights Reserved
Designed by Prayer Time In Dubai