Surah Aal-e-Imran Verse 140 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Aal-e-Imranإِن يَمۡسَسۡكُمۡ قَرۡحٞ فَقَدۡ مَسَّ ٱلۡقَوۡمَ قَرۡحٞ مِّثۡلُهُۥۚ وَتِلۡكَ ٱلۡأَيَّامُ نُدَاوِلُهَا بَيۡنَ ٱلنَّاسِ وَلِيَعۡلَمَ ٱللَّهُ ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ وَيَتَّخِذَ مِنكُمۡ شُهَدَآءَۗ وَٱللَّهُ لَا يُحِبُّ ٱلظَّـٰلِمِينَ
Ti ipalara kan ba kan yin, iru ipalara bee kuku ti kan ijo keferi. Awon ojo wonyi, A n yi i po laaarin awon eniyan ni. Ati pe nitori ki Allahu le se afihan awon t’o gbagbo ni ododo ati nitori ki O le (tewo) gba awon t’o maa ku fun Un ninu yin. Allahu ko si nifee awon alabosi