Surah Aal-e-Imran Verse 146 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Aal-e-Imranوَكَأَيِّن مِّن نَّبِيّٖ قَٰتَلَ مَعَهُۥ رِبِّيُّونَ كَثِيرٞ فَمَا وَهَنُواْ لِمَآ أَصَابَهُمۡ فِي سَبِيلِ ٱللَّهِ وَمَا ضَعُفُواْ وَمَا ٱسۡتَكَانُواْۗ وَٱللَّهُ يُحِبُّ ٱلصَّـٰبِرِينَ
Meloo meloo ninu awon Anabi ti won ti jagun esin pelu opolopo omo-eyin (won). Won ko ni irewesi okan nipa ohun ti o sele si won ni oju ogun esin Allahu. Won ko kole, won ko si jura won sile fun ota esin. Allahu si nifee awon onisuuru