Surah Aal-e-Imran Verse 20 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Aal-e-Imranفَإِنۡ حَآجُّوكَ فَقُلۡ أَسۡلَمۡتُ وَجۡهِيَ لِلَّهِ وَمَنِ ٱتَّبَعَنِۗ وَقُل لِّلَّذِينَ أُوتُواْ ٱلۡكِتَٰبَ وَٱلۡأُمِّيِّـۧنَ ءَأَسۡلَمۡتُمۡۚ فَإِنۡ أَسۡلَمُواْ فَقَدِ ٱهۡتَدَواْۖ وَّإِن تَوَلَّوۡاْ فَإِنَّمَا عَلَيۡكَ ٱلۡبَلَٰغُۗ وَٱللَّهُ بَصِيرُۢ بِٱلۡعِبَادِ
Ti won ba si ja o niyan, so pe: “Emi ati eni ti o tele mi juwo juse sile fun Allahu.” Ki o si so fun awon ti A fun ni Tira ati awon alaimoonkomoonka (alainitira) pe: “Se e maa gba ’Islam?” Ti won ba gba ’Islam, won ti mona. Ti won ba si keyin (si ’Islam), ise-jije nikan ni ojuse tire. Allahu si ni Oluriran nipa awon erusin