Surah Aal-e-Imran Verse 45 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Aal-e-Imranإِذۡ قَالَتِ ٱلۡمَلَـٰٓئِكَةُ يَٰمَرۡيَمُ إِنَّ ٱللَّهَ يُبَشِّرُكِ بِكَلِمَةٖ مِّنۡهُ ٱسۡمُهُ ٱلۡمَسِيحُ عِيسَى ٱبۡنُ مَرۡيَمَ وَجِيهٗا فِي ٱلدُّنۡيَا وَٱلۡأٓخِرَةِ وَمِنَ ٱلۡمُقَرَّبِينَ
(E ranti) nigba ti awon molaika so pe: "Moryam, dajudaju Allahu n fun o ni iro idunnu (nipa dida eda kan pelu) oro kan lati odo Re. Oruko re ni Mosih ‘Isa omo Moryam. Abiyi ni ni aye ati ni orun. O si wa lara alasun-unmo (Allahu). ninu ayah ti ali ‘Imron Allahu (subhanahu wa ta'ala) n so nipa bi awon mola’ikah se wa so asotele nipa bibi ‘Isa ('alaehi-ssolatu wa-ssalam). Awon molaika t’o wa so asotele naa ju eyo kan lo. Idi niyi ti “mola’ikah” fi je opo ninu ayah yen. Amo ninu ayah ti Moryam