Surah Aal-e-Imran Verse 73 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Aal-e-Imranوَلَا تُؤۡمِنُوٓاْ إِلَّا لِمَن تَبِعَ دِينَكُمۡ قُلۡ إِنَّ ٱلۡهُدَىٰ هُدَى ٱللَّهِ أَن يُؤۡتَىٰٓ أَحَدٞ مِّثۡلَ مَآ أُوتِيتُمۡ أَوۡ يُحَآجُّوكُمۡ عِندَ رَبِّكُمۡۗ قُلۡ إِنَّ ٱلۡفَضۡلَ بِيَدِ ٱللَّهِ يُؤۡتِيهِ مَن يَشَآءُۗ وَٱللَّهُ وَٰسِعٌ عَلِيمٞ
(Won tun wi pe:) “E ma gbagbo ayafi eni ti o ba tele esin yin.” So pe: “Dajudaju imona (’Islam) ni imona ti Allahu.” (Won tun wi pe:) “(E ma gbagbo) pe won fun eni kan ni iru ohun ti Won fun yin tabi pe won yoo tako yin (ti won yo si jare yin) lodo Oluwa yin.” So pe: “Dajudaju oore ajulo wa ni owo Allahu. O n fun eni ti O ba fe. Allahu ni Olugbaaye, Onimo.”