Surah Aal-e-Imran Verse 86 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Aal-e-Imranكَيۡفَ يَهۡدِي ٱللَّهُ قَوۡمٗا كَفَرُواْ بَعۡدَ إِيمَٰنِهِمۡ وَشَهِدُوٓاْ أَنَّ ٱلرَّسُولَ حَقّٞ وَجَآءَهُمُ ٱلۡبَيِّنَٰتُۚ وَٱللَّهُ لَا يَهۡدِي ٱلۡقَوۡمَ ٱلظَّـٰلِمِينَ
Bawo ni Allahu yo se fi ona mo ijo kan t’o sai gbagbo leyin igbagbo won? Won si jerii pe dajudaju Ojise naa, ododo ni. Awon eri t’o yanju si ti de ba won. Allahu ki i fi ona mo ijo alabosi