Surah Aal-e-Imran Verse 91 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Aal-e-Imranإِنَّ ٱلَّذِينَ كَفَرُواْ وَمَاتُواْ وَهُمۡ كُفَّارٞ فَلَن يُقۡبَلَ مِنۡ أَحَدِهِم مِّلۡءُ ٱلۡأَرۡضِ ذَهَبٗا وَلَوِ ٱفۡتَدَىٰ بِهِۦٓۗ أُوْلَـٰٓئِكَ لَهُمۡ عَذَابٌ أَلِيمٞ وَمَا لَهُم مِّن نَّـٰصِرِينَ
Dajudaju awon t’o sai gbagbo, ti won si ku nigba ti won je alaigbagbo, A o nii gba ekun ile wura lowo enikeni ninu won, ibaa fi serapada (fun emi ara re nibi Ina). Awon wonyen ni iya eleta-elero n be fun. Ko si nii si awon oluranlowo fun won