Surah An-Nisa Verse 1 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah An-Nisaيَـٰٓأَيُّهَا ٱلنَّاسُ ٱتَّقُواْ رَبَّكُمُ ٱلَّذِي خَلَقَكُم مِّن نَّفۡسٖ وَٰحِدَةٖ وَخَلَقَ مِنۡهَا زَوۡجَهَا وَبَثَّ مِنۡهُمَا رِجَالٗا كَثِيرٗا وَنِسَآءٗۚ وَٱتَّقُواْ ٱللَّهَ ٱلَّذِي تَسَآءَلُونَ بِهِۦ وَٱلۡأَرۡحَامَۚ إِنَّ ٱللَّهَ كَانَ عَلَيۡكُمۡ رَقِيبٗا
Eyin eniyan, e beru Oluwa yin, Eni ti O seda yin lati ara emi eyo kan (iyen, Anabi Adam). O si seda aya re (Hawa’) lati ara re. O fon opolopo okunrin ati obinrin jade lati ara awon mejeeji. Ki e si beru Allahu, Eni ti e n fi be ara yin. (E so) okun-ibi. Dajudaju Allahu n je Oluso lori yin