Surah An-Nisa Verse 140 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah An-Nisaوَقَدۡ نَزَّلَ عَلَيۡكُمۡ فِي ٱلۡكِتَٰبِ أَنۡ إِذَا سَمِعۡتُمۡ ءَايَٰتِ ٱللَّهِ يُكۡفَرُ بِهَا وَيُسۡتَهۡزَأُ بِهَا فَلَا تَقۡعُدُواْ مَعَهُمۡ حَتَّىٰ يَخُوضُواْ فِي حَدِيثٍ غَيۡرِهِۦٓ إِنَّكُمۡ إِذٗا مِّثۡلُهُمۡۗ إِنَّ ٱللَّهَ جَامِعُ ٱلۡمُنَٰفِقِينَ وَٱلۡكَٰفِرِينَ فِي جَهَنَّمَ جَمِيعًا
(Allahu) kuku ti so o kale fun yin ninu Tira pe nigba ti e ba gbo nipa awon ayah Allahu pe won n sai gbagbo ninu re, won si n fi se efe, e ma se jokoo ti won nigba naa titi won yoo fi bo sinu oro miiran, bi bee ko dajudaju eyin yoo da bi iru won. Dajudaju Allahu yoo pa awon sobe-selu musulumi po mo gbogbo awon alaigbagbo ninu ina Jahanamo