Surah An-Nisa Verse 37 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah An-Nisaٱلَّذِينَ يَبۡخَلُونَ وَيَأۡمُرُونَ ٱلنَّاسَ بِٱلۡبُخۡلِ وَيَكۡتُمُونَ مَآ ءَاتَىٰهُمُ ٱللَّهُ مِن فَضۡلِهِۦۗ وَأَعۡتَدۡنَا لِلۡكَٰفِرِينَ عَذَابٗا مُّهِينٗا
Àwọn t’ó ń ṣahun, (àwọn) t’ó ń pa ènìyàn láṣẹ ahun ṣíṣe àti (àwọn) t’ó ń fi ohun tí Allāhu fún wọn nínú oore àjùlọ Rẹ̀ pamọ́; A ti pèsè ìyà tí í yẹpẹrẹ ẹ̀dá sílẹ̀ de àwọn aláìgbàgbọ́