Surah An-Nisa Verse 39 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah An-Nisaوَمَاذَا عَلَيۡهِمۡ لَوۡ ءَامَنُواْ بِٱللَّهِ وَٱلۡيَوۡمِ ٱلۡأٓخِرِ وَأَنفَقُواْ مِمَّا رَزَقَهُمُ ٱللَّهُۚ وَكَانَ ٱللَّهُ بِهِمۡ عَلِيمًا
Ki ni ipalara ti o maa se fun won ti won ba gbagbo ninu Allahu ati Ojo Ikeyin, ti won si na ninu ohun ti Allahu se ni arisiki fun won? Allahu si je Onimo nipa won