Surah An-Nisa Verse 54 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah An-Nisaأَمۡ يَحۡسُدُونَ ٱلنَّاسَ عَلَىٰ مَآ ءَاتَىٰهُمُ ٱللَّهُ مِن فَضۡلِهِۦۖ فَقَدۡ ءَاتَيۡنَآ ءَالَ إِبۡرَٰهِيمَ ٱلۡكِتَٰبَ وَٱلۡحِكۡمَةَ وَءَاتَيۡنَٰهُم مُّلۡكًا عَظِيمٗا
Tabi won n se ilara awon eniyan lori ohun ti Allahu fun won ninu oore ajulo Re ni? Dajudaju A fun awon ebi (Anabi) ’Ibrohim ni Tira ati ijinle oye (sunnah). A si fun won ni ijoba t’o tobi