فَمِنۡهُم مَّنۡ ءَامَنَ بِهِۦ وَمِنۡهُم مَّن صَدَّ عَنۡهُۚ وَكَفَىٰ بِجَهَنَّمَ سَعِيرًا
Nítorí náà, ó ń bẹ nínú wọn ẹni t’ó gbàgbọ́ nínú rẹ̀. Ó sì ń bẹ nínú wọn ẹni t’ó ṣẹ́rí kúrò níbẹ̀. Jahanamọ sì tó ní iná t’ó ń jò
Author: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni