Surah An-Nisa Verse 69 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah An-Nisaوَمَن يُطِعِ ٱللَّهَ وَٱلرَّسُولَ فَأُوْلَـٰٓئِكَ مَعَ ٱلَّذِينَ أَنۡعَمَ ٱللَّهُ عَلَيۡهِم مِّنَ ٱلنَّبِيِّـۧنَ وَٱلصِّدِّيقِينَ وَٱلشُّهَدَآءِ وَٱلصَّـٰلِحِينَۚ وَحَسُنَ أُوْلَـٰٓئِكَ رَفِيقٗا
Enikeni ti o ba tele (ase) Allahu ati (ase) Ojise naa, awon wonyen maa wa (ninu Ogba Idera) pelu awon ti Allahu sedera fun ninu awon Anabi, awon olododo, awon t’o ku s’oju ogun esin ati awon eni rere. Awon wonyen si dara ni alabaarin