Surah An-Nisa Verse 85 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah An-Nisaمَّن يَشۡفَعۡ شَفَٰعَةً حَسَنَةٗ يَكُن لَّهُۥ نَصِيبٞ مِّنۡهَاۖ وَمَن يَشۡفَعۡ شَفَٰعَةٗ سَيِّئَةٗ يَكُن لَّهُۥ كِفۡلٞ مِّنۡهَاۗ وَكَانَ ٱللَّهُ عَلَىٰ كُلِّ شَيۡءٖ مُّقِيتٗا
Ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣìpẹ̀ ìṣìpẹ̀ rere, ó máa rí ìpín ẹ̀san nínú rẹ̀. Ẹnikẹ́ni tí ó bá sì ṣìpẹ̀ ìṣìpẹ̀ aburú, ó máa rí ìpín ẹ̀ṣẹ̀ nínú rẹ̀. Allāhu sì jẹ́ Olùṣọ́ lórí gbogbo n̄ǹkan