Surah An-Nisa Verse 97 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah An-Nisaإِنَّ ٱلَّذِينَ تَوَفَّىٰهُمُ ٱلۡمَلَـٰٓئِكَةُ ظَالِمِيٓ أَنفُسِهِمۡ قَالُواْ فِيمَ كُنتُمۡۖ قَالُواْ كُنَّا مُسۡتَضۡعَفِينَ فِي ٱلۡأَرۡضِۚ قَالُوٓاْ أَلَمۡ تَكُنۡ أَرۡضُ ٱللَّهِ وَٰسِعَةٗ فَتُهَاجِرُواْ فِيهَاۚ فَأُوْلَـٰٓئِكَ مَأۡوَىٰهُمۡ جَهَنَّمُۖ وَسَآءَتۡ مَصِيرًا
Dajudaju awon ti molaika gba emi won, (lasiko) ti won n sabosi si emi ara won, (awon molaika) so pe: “Ki ni e n se (ninu esin)?” Won wi pe: “Won da wa lagara lori ile ni.” (Awon molaika) so pe: “Se ile Allahu ko fe to (fun yin) lati gbe esin yin sa lori ile?” Awon wonyen, ina Jahanamo ni ibugbe won. O si buru ni ikangun