Surah Al-Maeda Verse 31 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Maedaفَبَعَثَ ٱللَّهُ غُرَابٗا يَبۡحَثُ فِي ٱلۡأَرۡضِ لِيُرِيَهُۥ كَيۡفَ يُوَٰرِي سَوۡءَةَ أَخِيهِۚ قَالَ يَٰوَيۡلَتَىٰٓ أَعَجَزۡتُ أَنۡ أَكُونَ مِثۡلَ هَٰذَا ٱلۡغُرَابِ فَأُوَٰرِيَ سَوۡءَةَ أَخِيۖ فَأَصۡبَحَ مِنَ ٱلنَّـٰدِمِينَ
Allāhu sì gbé ẹyẹ kannakánná kan dìde. Ó sì ń fi ẹsẹ̀ wa ilẹ̀ nítorí kí ó lè fi bí ó ṣe máa bo òkú arákùnrin rẹ̀ mọ́ inú ilẹ̀ hàn án. Ó wí pé: “Tèmi bàjẹ́ o! Mo kágara láti dà bí irú ẹyẹ kannakánná yìí, kí n̄g sì lè bo òkú arákùnrin mi mọ́lẹ̀.” Ó sì di ara àwọn alábàámọ̀