Surah Al-Maeda Verse 36 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Maedaإِنَّ ٱلَّذِينَ كَفَرُواْ لَوۡ أَنَّ لَهُم مَّا فِي ٱلۡأَرۡضِ جَمِيعٗا وَمِثۡلَهُۥ مَعَهُۥ لِيَفۡتَدُواْ بِهِۦ مِنۡ عَذَابِ يَوۡمِ ٱلۡقِيَٰمَةِ مَا تُقُبِّلَ مِنۡهُمۡۖ وَلَهُمۡ عَذَابٌ أَلِيمٞ
Dajudaju awon t’o sai gbagbo, ti o ba je pe gbogbo ohun ti n be lori ile aye patapata je tiwon ati iru re pelu re lati fi gba ara won sile nibi iya Ojo Ajinde, A o nii gba a ni owo won. Iya eleta-elero si wa fun won