Surah Al-Maeda Verse 70 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Maedaلَقَدۡ أَخَذۡنَا مِيثَٰقَ بَنِيٓ إِسۡرَـٰٓءِيلَ وَأَرۡسَلۡنَآ إِلَيۡهِمۡ رُسُلٗاۖ كُلَّمَا جَآءَهُمۡ رَسُولُۢ بِمَا لَا تَهۡوَىٰٓ أَنفُسُهُمۡ فَرِيقٗا كَذَّبُواْ وَفَرِيقٗا يَقۡتُلُونَ
A kuku gba adehun lowo awon omo ’Isro’il. A si ran awon Ojise kan si won. Igbakigba ti Ojise kan ba de ba won pelu ohun ti emi won ko fe, won pe igun kan ni opuro, won si n pa igun kan