Surah Al-Maeda Verse 81 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Maedaوَلَوۡ كَانُواْ يُؤۡمِنُونَ بِٱللَّهِ وَٱلنَّبِيِّ وَمَآ أُنزِلَ إِلَيۡهِ مَا ٱتَّخَذُوهُمۡ أَوۡلِيَآءَ وَلَٰكِنَّ كَثِيرٗا مِّنۡهُمۡ فَٰسِقُونَ
Ti o ba je pe won gbagbo ninu Allahu ati Anabi (sollalahu 'alayhi wa sallam), ati ohun ti A sokale fun un, won ko nii mu won ni ore ayo, sugbon opolopo ninu won ni obileje