Surah Al-Maeda Verse 85 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Maedaفَأَثَٰبَهُمُ ٱللَّهُ بِمَا قَالُواْ جَنَّـٰتٖ تَجۡرِي مِن تَحۡتِهَا ٱلۡأَنۡهَٰرُ خَٰلِدِينَ فِيهَاۚ وَذَٰلِكَ جَزَآءُ ٱلۡمُحۡسِنِينَ
Nitori naa, nitori ohun ti won so, Allahu san won ni esan pelu awon Ogba Idera, ti awon odo n san ni isale re. Olusegbere ni won ninu re. Iyen si ni esan fun awon oluse-rere