Surah Al-Anaam Verse 105 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Anaamوَكَذَٰلِكَ نُصَرِّفُ ٱلۡأٓيَٰتِ وَلِيَقُولُواْ دَرَسۡتَ وَلِنُبَيِّنَهُۥ لِقَوۡمٖ يَعۡلَمُونَ
Báyẹn ni A ṣe ń mú àwọn āyah wá lóníran-ànran ọ̀nà nítorí kí wọ́n lè wí pé: "O kẹ́kọ̀ọ́ (rẹ̀ lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn ni." Dípò kí wọ́n wí pé: "Wọ́n sọ̀ ọ́ kalẹ̀ fún ọ ni." àti nítorí kí A lè ṣe àlàyé rẹ̀ fún àwọn ènìyàn t’ó nímọ̀)