إِنَّ رَبَّكَ هُوَ أَعۡلَمُ مَن يَضِلُّ عَن سَبِيلِهِۦۖ وَهُوَ أَعۡلَمُ بِٱلۡمُهۡتَدِينَ
Dájúdájú Olúwa rẹ, Òun l’Ó nímọ̀ jùlọ nípa ẹni t’ó ṣìnà lójú ọ̀nà (ẹ̀sìn) Rẹ̀. Àti pé, Òun sì l’Ó nímọ̀ jùlọ nípa àwọn olùmọ̀nà
Author: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni