Surah Al-Anaam Verse 12 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Anaamقُل لِّمَن مَّا فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِۖ قُل لِّلَّهِۚ كَتَبَ عَلَىٰ نَفۡسِهِ ٱلرَّحۡمَةَۚ لَيَجۡمَعَنَّكُمۡ إِلَىٰ يَوۡمِ ٱلۡقِيَٰمَةِ لَا رَيۡبَ فِيهِۚ ٱلَّذِينَ خَسِرُوٓاْ أَنفُسَهُمۡ فَهُمۡ لَا يُؤۡمِنُونَ
So pe: “Ti ta ni ohunkohun t’o wa ninu awon sanmo ati ile?” So pe: “Ti Allahu ni.” O se aanu ni oran-anyan lera Re lori. Dajudaju O maa ko yin jo ni Ojo Ajinde, ko si iyemeji ninu re. Awon t’o se emi won lofo (sinu aigbagbo), won ko nii gbagbo