Surah Al-Anaam Verse 128 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Anaamوَيَوۡمَ يَحۡشُرُهُمۡ جَمِيعٗا يَٰمَعۡشَرَ ٱلۡجِنِّ قَدِ ٱسۡتَكۡثَرۡتُم مِّنَ ٱلۡإِنسِۖ وَقَالَ أَوۡلِيَآؤُهُم مِّنَ ٱلۡإِنسِ رَبَّنَا ٱسۡتَمۡتَعَ بَعۡضُنَا بِبَعۡضٖ وَبَلَغۡنَآ أَجَلَنَا ٱلَّذِيٓ أَجَّلۡتَ لَنَاۚ قَالَ ٱلنَّارُ مَثۡوَىٰكُمۡ خَٰلِدِينَ فِيهَآ إِلَّا مَا شَآءَ ٱللَّهُۚ إِنَّ رَبَّكَ حَكِيمٌ عَلِيمٞ
(Ranti) Ojo ti (Allahu) yoo ko gbogbo won jo patapata, (O maa so pe): “Eyin awujo alujannu, dajudaju e ti ko opolopo eniyan sonu.” Awon ore won ninu awon eniyan yoo wi pe: “Oluwa wa, apa kan wa gbadun apa kan ni. A si ti lo asiko wa ti O bu fun wa (lati lo).” (Allahu) so pe: “Ina ni ibugbe yin; olusegbere ni yin ninu re afi ohun ti Allahu ba fe . Dajudaju Oluwa re ni Ologbon, Onimo