Surah Al-Anaam Verse 130 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Anaamيَٰمَعۡشَرَ ٱلۡجِنِّ وَٱلۡإِنسِ أَلَمۡ يَأۡتِكُمۡ رُسُلٞ مِّنكُمۡ يَقُصُّونَ عَلَيۡكُمۡ ءَايَٰتِي وَيُنذِرُونَكُمۡ لِقَآءَ يَوۡمِكُمۡ هَٰذَاۚ قَالُواْ شَهِدۡنَا عَلَىٰٓ أَنفُسِنَاۖ وَغَرَّتۡهُمُ ٱلۡحَيَوٰةُ ٱلدُّنۡيَا وَشَهِدُواْ عَلَىٰٓ أَنفُسِهِمۡ أَنَّهُمۡ كَانُواْ كَٰفِرِينَ
Eyin awujo alujannu ati eniyan, se awon Ojise kan laaarin yin ko wa ba yin, ti won n ke awon ayah Mi fun yin, ti won si n fi ipade yin Oni yii sekilo fun yin? Won wi pe: “A jerii lera wa lori (pe won wa).” Isemi aye tan won je. Won si jerii lera won lori pe dajudaju awon je alaigbagbo