Surah Al-Anaam Verse 14 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Anaamقُلۡ أَغَيۡرَ ٱللَّهِ أَتَّخِذُ وَلِيّٗا فَاطِرِ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِ وَهُوَ يُطۡعِمُ وَلَا يُطۡعَمُۗ قُلۡ إِنِّيٓ أُمِرۡتُ أَنۡ أَكُونَ أَوَّلَ مَنۡ أَسۡلَمَۖ وَلَا تَكُونَنَّ مِنَ ٱلۡمُشۡرِكِينَ
So pe: “Se ki ng mu oluranlowo kan yato si Allahu, Eledaa awon sanmo ati ile? Oun si ni O n bo (eda), won ki i bo O.” So pe: “Dajudaju Won pa mi lase pe ki ng je eni akoko ti o maa se ’Islam (ni asiko temi).” Iwo ko si gbodo wa ninu awon osebo. ofin Re ati ilana Re. Eyi ni awon kan mo si “sise ife-Olohun”. Ewo ninu awon Anabi Olohun ati Ojise Re ni ko juwo-juse sile patapata fun ase Allahu ofin Re ati ilana Re? Ewo ninu won se ni ko se ife-Olohun? Ko si. Idi niyi ti gbogbo won fi je musulumi gege bi Allahu (subhanahu wa ta'ala) se fi rinle ninu surah al-Baƙorah; 2:128-141. ofin Re ati ilana Re. Amo ninu ijo re oun ni eni akoko ti o koko se bee