Surah Al-Anaam Verse 145 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Anaamقُل لَّآ أَجِدُ فِي مَآ أُوحِيَ إِلَيَّ مُحَرَّمًا عَلَىٰ طَاعِمٖ يَطۡعَمُهُۥٓ إِلَّآ أَن يَكُونَ مَيۡتَةً أَوۡ دَمٗا مَّسۡفُوحًا أَوۡ لَحۡمَ خِنزِيرٖ فَإِنَّهُۥ رِجۡسٌ أَوۡ فِسۡقًا أُهِلَّ لِغَيۡرِ ٱللَّهِ بِهِۦۚ فَمَنِ ٱضۡطُرَّ غَيۡرَ بَاغٖ وَلَا عَادٖ فَإِنَّ رَبَّكَ غَفُورٞ رَّحِيمٞ
So pe: "Emi ko ri ninu ohun ti Won fi ranse si mi ti Won se jije re ni eewo fun eni ti o n je e afi ohun ti o ba je eran okunbete tabi eje sisan,1 tabi eran elede nitori pe dajudaju egbin ni, tabi eran iyapa (ase Allahu) ti won pa pelu oruko t’o yato si Allahu. Nitori naa, enikeni ti inira (ebi) ba mu je e, yato si eni t’o n wa eewo kiri ati olutayo-enu-ala, dajudaju Oluwa re ni Alaforijin, Asake-orun