Surah Al-Anaam Verse 2 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Anaamهُوَ ٱلَّذِي خَلَقَكُم مِّن طِينٖ ثُمَّ قَضَىٰٓ أَجَلٗاۖ وَأَجَلٞ مُّسَمًّى عِندَهُۥۖ ثُمَّ أَنتُمۡ تَمۡتَرُونَ
Òun ni Ẹni tí Ó da yín láti inú erùpẹ̀ amọ̀. Lẹ́yìn náà, Ó fi gbèdéke ìgbà kan sí (ìṣẹ̀mí ayé yín). Àti pé gbèdéké àkókò kan (tún wà fún ayé) lọ́dọ̀ Rẹ̀. Lẹ́yìn náà, ẹ tún ń ṣeyèméjì