Surah Al-Anaam Verse 80 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Anaamوَحَآجَّهُۥ قَوۡمُهُۥۚ قَالَ أَتُحَـٰٓجُّوٓنِّي فِي ٱللَّهِ وَقَدۡ هَدَىٰنِۚ وَلَآ أَخَافُ مَا تُشۡرِكُونَ بِهِۦٓ إِلَّآ أَن يَشَآءَ رَبِّي شَيۡـٔٗاۚ وَسِعَ رَبِّي كُلَّ شَيۡءٍ عِلۡمًاۚ أَفَلَا تَتَذَكَّرُونَ
Awon eniyan re si ja a niyan. O so pe: "Se eyin yoo ja mi niyan nipa Allahu, O si ti fi ona mo mi? Emi ko si paya (awon orisa) ti e so di akegbe fun Un, afi bi Allahu ba fe kini kan (pe ko sele). Oluwa mi fi imo gbooro ju gbogbo nnkan. Nitori naa, se e o nii lo iranti ni