Surah Al-Kafiroon - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
قُلۡ يَـٰٓأَيُّهَا ٱلۡكَٰفِرُونَ
Sọ pé: "Ẹ̀yin aláìgbàgbọ́
Surah Al-Kafiroon, Verse 1
لَآ أَعۡبُدُ مَا تَعۡبُدُونَ
Èmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ̀ ń jọ́sìn fún
Surah Al-Kafiroon, Verse 2
وَلَآ أَنتُمۡ عَٰبِدُونَ مَآ أَعۡبُدُ
Ẹ̀yin náà kò jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún
Surah Al-Kafiroon, Verse 3
وَلَآ أَنَا۠ عَابِدٞ مَّا عَبَدتُّمۡ
Èmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ jọ́sìn fún sẹ́
Surah Al-Kafiroon, Verse 4
وَلَآ أَنتُمۡ عَٰبِدُونَ مَآ أَعۡبُدُ
Ẹ̀yin náà kò kú jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún
Surah Al-Kafiroon, Verse 5
لَكُمۡ دِينُكُمۡ وَلِيَ دِينِ
Tiyín ni ẹ̀sìn yín, tèmi sì ni ẹ̀sìn mi
Surah Al-Kafiroon, Verse 6