Surah Al-Baqara Verse 13 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqaraوَإِذَا قِيلَ لَهُمۡ ءَامِنُواْ كَمَآ ءَامَنَ ٱلنَّاسُ قَالُوٓاْ أَنُؤۡمِنُ كَمَآ ءَامَنَ ٱلسُّفَهَآءُۗ أَلَآ إِنَّهُمۡ هُمُ ٱلسُّفَهَآءُ وَلَٰكِن لَّا يَعۡلَمُونَ
Nigba ti won ba so fun won pe: “E gbagbo ni ododo gege bi awon eniyan se gbagbo.” Won a wi pe: “Se ki a gbagbo gege bi awon omugo se gbagbo ni?” E kiye si i! Dajudaju awon gan-an ni omugo, sugbon won ko mo