Surah Al-Baqara Verse 14 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqaraوَإِذَا لَقُواْ ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ قَالُوٓاْ ءَامَنَّا وَإِذَا خَلَوۡاْ إِلَىٰ شَيَٰطِينِهِمۡ قَالُوٓاْ إِنَّا مَعَكُمۡ إِنَّمَا نَحۡنُ مُسۡتَهۡزِءُونَ
Nigba ti won ba pade awon t’o gbagbo ni ododo, won a wi pe: “A gbagbo.” Nigba ti o ba si ku won ku awon (eni) esu won, won a wi pe: “Dajudaju awa n be pelu yin, awa kan n se yeye ni.”