Surah Al-Baqara Verse 15 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqaraٱللَّهُ يَسۡتَهۡزِئُ بِهِمۡ وَيَمُدُّهُمۡ فِي طُغۡيَٰنِهِمۡ يَعۡمَهُونَ
Allahu maa fi won se yeye. O si maa mu won lekun si i ninu agbere won, ti won yoo maa pa ridarida. ti awon ise naa je ise t’o duro sori fifi oruko ise eda so oruko esan ise naa. Iru re l’o sele ninu ayah ti a n tose re lowo yii. Allahu (subhanahu wa ta'ala) ki i se oluseyeye (eni ti o maa n se yeye) tabi oniyeye (eni ti eda le fi se yeye). Eni kan ko si nii maa se yeye afi ki o je alawada oniranu. Allahu (subhanahu wa ta'ala) ki i se awada Allahu ki i se eletan. Eni kan ko nii je eletan afi ki o je opuro oluyapa-adehun. Allahu ki i se opuro. Allahu gan-an ni Ododo. Bakan naa