Surah Al-Baqara Verse 186 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqaraوَإِذَا سَأَلَكَ عِبَادِي عَنِّي فَإِنِّي قَرِيبٌۖ أُجِيبُ دَعۡوَةَ ٱلدَّاعِ إِذَا دَعَانِۖ فَلۡيَسۡتَجِيبُواْ لِي وَلۡيُؤۡمِنُواْ بِي لَعَلَّهُمۡ يَرۡشُدُونَ
Nigba ti awon erusin Mi ba bi o leere nipa Mi, dajudaju Emi ni Olusunmo. Emi yoo jepe adua aladuua nigba ti o ba pe Mi. Ki won je’pe Mi (nipa itele ase Mi). Ki won si gba Mi gbo nitori ki won le mona (gbigba adua)