Surah Al-Baqara Verse 25 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqaraوَبَشِّرِ ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ وَعَمِلُواْ ٱلصَّـٰلِحَٰتِ أَنَّ لَهُمۡ جَنَّـٰتٖ تَجۡرِي مِن تَحۡتِهَا ٱلۡأَنۡهَٰرُۖ كُلَّمَا رُزِقُواْ مِنۡهَا مِن ثَمَرَةٖ رِّزۡقٗا قَالُواْ هَٰذَا ٱلَّذِي رُزِقۡنَا مِن قَبۡلُۖ وَأُتُواْ بِهِۦ مُتَشَٰبِهٗاۖ وَلَهُمۡ فِيهَآ أَزۡوَٰجٞ مُّطَهَّرَةٞۖ وَهُمۡ فِيهَا خَٰلِدُونَ
Fun awon t’o gbagbo ni ododo, ti won si se awon ise rere ni iro idunnu pe, dajudaju awon Ogba Idera kan n be fun won, eyi ti awon odo n san ni isale re. Nigbakigba ti A ba p’ese jije-mimu kan fun won ninu eso re, won yoo so pe: “Eyi ni won ti pese fun wa teletele.” – Won mu un wa fun won ni irisi kan naa ni (amo pelu adun otooto). – Awon iyawo mimo si n be fun won ninu Ogba Idera. Olusegbere si ni won ninu re