Surah Al-Baqara Verse 26 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqara۞إِنَّ ٱللَّهَ لَا يَسۡتَحۡيِۦٓ أَن يَضۡرِبَ مَثَلٗا مَّا بَعُوضَةٗ فَمَا فَوۡقَهَاۚ فَأَمَّا ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ فَيَعۡلَمُونَ أَنَّهُ ٱلۡحَقُّ مِن رَّبِّهِمۡۖ وَأَمَّا ٱلَّذِينَ كَفَرُواْ فَيَقُولُونَ مَاذَآ أَرَادَ ٱللَّهُ بِهَٰذَا مَثَلٗاۘ يُضِلُّ بِهِۦ كَثِيرٗا وَيَهۡدِي بِهِۦ كَثِيرٗاۚ وَمَا يُضِلُّ بِهِۦٓ إِلَّا ٱلۡفَٰسِقِينَ
Dajudaju Allahu ko nii tiju lati fi ohun kan bi efon tabi ohun ti o ju u lo sakawe oro. Ni ti awon t’o gbagbo ni ododo, won yoo mo pe dajudaju ododo ni lati odo Oluwa won. Ni ti awon t’o sai gbagbo, won yoo wi pe: “Ki ni ohun ti Allahu gba lero pelu akawe yii?” Allahu n fi si lona. O si n fi to opolopo sona. Ko si nii fi si enikeni lona ayafi awon arufin