وَٱتَّقُواْ يَوۡمٗا تُرۡجَعُونَ فِيهِ إِلَى ٱللَّهِۖ ثُمَّ تُوَفَّىٰ كُلُّ نَفۡسٖ مَّا كَسَبَتۡ وَهُمۡ لَا يُظۡلَمُونَ
E beru ojo kan ti won maa da yin pada si odo Allahu. Leyin naa, Won maa san emi kookan ni esan ni ekun rere (nipa) ohun ti o se nise. Won ko si nii sabosi si won
Author: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni