Surah Al-Baqara Verse 285 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqaraءَامَنَ ٱلرَّسُولُ بِمَآ أُنزِلَ إِلَيۡهِ مِن رَّبِّهِۦ وَٱلۡمُؤۡمِنُونَۚ كُلٌّ ءَامَنَ بِٱللَّهِ وَمَلَـٰٓئِكَتِهِۦ وَكُتُبِهِۦ وَرُسُلِهِۦ لَا نُفَرِّقُ بَيۡنَ أَحَدٖ مِّن رُّسُلِهِۦۚ وَقَالُواْ سَمِعۡنَا وَأَطَعۡنَاۖ غُفۡرَانَكَ رَبَّنَا وَإِلَيۡكَ ٱلۡمَصِيرُ
Ojise naa (sollalahu 'alayhi wa sallam) gbagbo ninu ohun ti won sokale fun un lati odo Oluwa re. Awon onigbagbo ododo naa (gbagbo ninu re). Eni kookan (won) gbagbo ninu Allahu, awon molaika Re, awon Tira Re ati awon Ojise Re. A ko ya eni kan soto ninu awon Ojise Re. Won si so pe: “A gbo (ase), a si tele (ase). A n toro aforijin Re, Oluwa wa. Odo Re si ni abo eda.”