Surah Al-Baqara Verse 90 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqaraبِئۡسَمَا ٱشۡتَرَوۡاْ بِهِۦٓ أَنفُسَهُمۡ أَن يَكۡفُرُواْ بِمَآ أَنزَلَ ٱللَّهُ بَغۡيًا أَن يُنَزِّلَ ٱللَّهُ مِن فَضۡلِهِۦ عَلَىٰ مَن يَشَآءُ مِنۡ عِبَادِهِۦۖ فَبَآءُو بِغَضَبٍ عَلَىٰ غَضَبٖۚ وَلِلۡكَٰفِرِينَ عَذَابٞ مُّهِينٞ
Aburu ni ohun ti won ra fun emi ara won nipa bi won se sai gbagbo ninu ohun ti Allahu sokale, ni ti ilara pe Allahu n so (Tira) kale ninu oore ajulo Re fun eni ti O fe ninu awon erusin Re. Won si pada pelu ibinu (miiran) lori ibinu (Allahu ti o ti wa lori won tele). Iya ti i yepere (eda) si n be fun awon alaigbagbo