Surah Al-Baqara Verse 91 - Yoruba Translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Surah Al-Baqaraوَإِذَا قِيلَ لَهُمۡ ءَامِنُواْ بِمَآ أَنزَلَ ٱللَّهُ قَالُواْ نُؤۡمِنُ بِمَآ أُنزِلَ عَلَيۡنَا وَيَكۡفُرُونَ بِمَا وَرَآءَهُۥ وَهُوَ ٱلۡحَقُّ مُصَدِّقٗا لِّمَا مَعَهُمۡۗ قُلۡ فَلِمَ تَقۡتُلُونَ أَنۢبِيَآءَ ٱللَّهِ مِن قَبۡلُ إِن كُنتُم مُّؤۡمِنِينَ
Nigba ti won ba so fun won pe: “E gbagbo ninu ohun ti Allahu sokale.” Won a wi pe: “A gbagbo ninu ohun ti won sokale fun wa.” Won si n sai gbagbo ninu ohun t’o wa leyin re, ti o si n fi ohun t’o je ododo rinle nipa eyi t’o wa pelu won. So pe: “Nitori ki ni e fi n pa awon Anabi Allahu teletele ti e ba je onigbagbo ododo